Oke Nla Nla by Okey Sokay (ft. Pst Bayo Adeyinka) is off His Album “RENEW”

Lyrics

OKE NLA NLA ( FT. BAYO ADEYINKA )
Oke nla nla
Oke we we
Iji lile
Koleduro niwaju re
Olorun e ti tobi to o
E tobi, Oluwa.
(Intro)
INSTRUMENTAL
( SOLO VERSE )

All mountains, great or small,
Strong and fearful,
Storms can never stand ,
Before You, Oh my God ,
How great You are ,
Oh Lord, how great You are.
All mountains, great or small,
Strong and fearful,
Storms can never stand ,
Before You, Oh my God ,
How great You are ,
Oh Lord, how great You are.
( SOLO CHORUS )
Oke nla nla
Oke we we
Iji lile
Koleduro niwaju re
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa
INTERLUDE
INSTRUMENTAL
( ALL VERSE )

All mountains, great or small,
Strong and fearful,
Storms can never stand ,
Before You, Oh my God ,
How great You are ,
Oh Lord, how great You are.
All mountains, great or small,
Strong and fearful,
Storms can never stand ,
Before You, Oh my God ,
How great You are ,
Oh Lord, how great You are.
( ALL CHORUS )

Oke nla nla
Oke we we
    Iji lile

Koleduro niwaju re
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa
Oke nla nla
Oke we we
Iji lile
Koleduro niwaju re
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa
( SOLO )
To the everlasting King
You, who sits upon the throne
And You reign forevermore
We declare You are great
You’re a great God
You’re a great God
(You are great)
You’re a great God
You’re a great God
(You are great)
You’re a great God
You’re a great God
(You are great)
(Yeah, Yeah)
(ORIKI)
Psalms (ORIN DAFIDI) 114: 1-8.
1 – Nigbati Israeli jade kuro ni Egipti,
ti ara-ile Jakobu kuro ninu àjeji ède enia;
• 2 – Juda di ibi mimọ́ rẹ̀, Israeli di ijọba rẹ̀.
• 3 – Okun ri i, o si sá: Jordani pada sẹhin.
• 4 – Awọn òke nla nfò bi àgbo, ati awọn òke kekèke bi ọdọ-agutan.
• 5 – Kili o ṣe ọ, iwọ okun, ti iwọ fi sá? iwọ Jordani ti iwọ fi pada sẹhin?

• 6 – Ẹnyin òke nla, ti ẹ fi nfò bi àgbo; ati ẹnyin òke kekèke bi ọdọ-
agutan?
• 7 – Warìri, iwọ ilẹ, niwaju Oluwa, niwaju Ọlọrun Jakobu.
• 8 – Ẹniti o sọ apata di adagun omi, ati okuta-ibọn di orisun omi.
( ALL CHORUS MODULATION )
Oke nla nla
Oke we we
Iji lile
Koleduro niwaju re
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa
Oke nla nla
Oke we we
Iji lile
Koleduro niwaju re
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa.
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa.
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa.
Olorun
e ti tobi to o
E tobi, Oluwa.
End

Video

Okey Sokay – Oke Nla Nla FT. Pst Bayo Adeyinka ( Official Video )

Shares:

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *