Jesu Olomi Ati Eje (Jehoshaphat) by Kay Wonder. Download and be Blessed.

Lyrics

Chorus-
Jesu olomi ati eje,
(Jesus the owner of water and blood)
Awuwo mama se ngbe
(Immovable God)
Okunrin ogun ti o se kolu,
(The man of war that cannot be contended with)
Gba wa lowo amunisin o,
(Save us from those that enslave us)
Jesu olomi ati eje,
(Jesus who owns the water and the blood)
Awuwo mama se ngbe
(Immovable king)
Okunrin ogun ti o se kolu,
(Man of war that cannot be contended with)
Gba wa o ati de,
(Save us, we have come)
.
Vocal-
Awon akorin nlo niwaju,
(Singers in front)
Awon oni fere, nfun fere,
(Trumpeters play their trumpet)
Oni duru ati ilu ko duro,
(Percussionists are not left out)
Niwaju ogun Amoni ati Moabu,
(In front of Amon and Moab’s war)
Jeoshaphati gbo’ohum some,
(Jehoshaphat raised his voice)
Oni e yin Oluwa,
(He said praise God)
Tori anu re o duro,
(For His mercies endures)
O duro o titi lai,
(It endures forever)
Oluwa kolu ogun Amoni and
Muabu,
(God collided with Amon and Moab’s battle )
Okun ni gbogbo won jasi,
(They all fell in the ocean)
Okunrin kan o ku ninu won,
(No man was left out)
Niwaju ogun Olorun baaba mi,
(In front of my father’s war)
Awa ti duro,
(We have waited)
Awa nwo ojurewo re,
(We look unto you)
Iwo to fi owo agbara gba Isreal Lowo faraho,
(You who by your power saved Isreal from the hands of Pharaoh)
,
Chorus-
Jesu olomi ati eje,
(Jesus the owner of water and blood)
Awuwo mama se ngbe
(Immovable God)
Okunrin ogun ti o se kolu,
(The man of war that cannot be contended with)
Gba wa lowo amunisin o,
(Save us from those that makes us sin)
Jesu olomi ati eje,
(Jesus who owns the water and the blood)
Awuwo mama se ngbe
(Immovable king)
Okunrin ogun ti o se kolu,
(Man of war that cannot be contended with)
Gba wa o ati de,
(Save us, we have come)
,.
.
Call!- Ologun ni yin, Jeovah
(Man of war, you are)
Res- ologun ni yin.
(Man of war, you are)
Olugbeja Orun ati ke wa so do re,
(Defender of heaven, we cry to you)
Fi ija f’awon to nbawaja,
(Fight those that fight us)
Gbesan wa lara ota,
(Avenge us of our enemies)
Gbawa lo wo amunisin Gba wa o ati de
(Save us from those that make us sin)
.
Gbanigbani lojo Ibi,
(Help in time of trouble)
Oba ayeraye,
(King forever)
Ko ma solorun miran lehin re,
(No other God except you)
Aba baba o e ma ga/2ce
(Abba father, you are great)
.
Vocal – Bawo le titobi to,
(How great you are)
Bawo le ti tobi to,
(How great you are)
Aye o gba yin Orun o gba yin,
Heaven and earth can’t contain you)
E faye s’apoti itise,
(You made the earth your footstool)
Anu yin Lati ayeraye,
(Your mercy from everlasting)
Agbara yin so oku d’alaye,
(Your power brought the dead to life)
Alade lori alade,
(The crown on the crowned)
Ijoye to ju ijoye lo,
(King maker above all king makers)
Asuwaju Ogun, Akehin ogun,
(The one in front and behind any war)
Jagunjagun mama lo ofaa,
(Mighty man of war)
O ke oko meji fi Keke ogun Jo’na,
(He used two carts to burn a great chariot of war)
Oluwa goke lo to’hun tariwo ogun nla,
(The Lord arises, he and the great noise of war)
Kabiyesi t’ohun ti iro Ipe,
(The king, He and the criers)
Arewa toju arewa lo,
(Beautiful beyond description)
Olola to ju olola,
(The wealthiest of all)
Ohun re nbe lori omi pupo,
(The king upon many waters)
Ohun oluwa ni ola nla ola nla,
(His voice is rich in great glory)
Ohun Oluwa mi aginju Kedeshi Lebanon,
(His voice breaks the cedars of Lebanon)
Ko mama s’olorun miran lehin re,
(There is king except you)
Aba baba o ema ga
(Abba father, you are great)

Video

Jesu Olomi Ati Eje (Jehoshaphat part2 ) – Kay Wonder @Invasion Praise Concert Season3

Shares:

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *